Bínútirí
Sísọ síta
Ìtumọọ Bínútirí
The way the mind is.
Àwọn àlàyé mìíràn
Full proverb: "Bí inú ti rí ni obì í yàn: As the mind is, so is the divination patterns of the kola."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bí-inú-ti-rí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bí - asinú - inside (of one's mind)
ti - appears to
rí - be like
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA