Bíntílayé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bíntílayé

Life is fragile.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bíntí-ni-ayé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bíntí - fleeting, fragile
ni - is
ayé - world, life, earth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO