Bílésanmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Bílésanmí

Make the home benefit me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-ilé-san-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - that
ilé - house, home
san - pay, benefit
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL