Bíbílarí

Sísọ síta



Ìtumọọ Bíbílarí

It's only his/her birth that we've seen.



Àwọn àlàyé mìíràn

An àbíkú name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bíbí-ni-a-rí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bíbí - the process of birthing
ni - is
a - we
rí - see, observe


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL