Bíbíire
Sísọ síta
Ìtumọọ Bíbíire
Noble/worthy birth is priceless.
Àwọn àlàyé mìíràn
This name is taken from a common Yorùbá saying, "Bíbíire kò ṣeé fi owó rà", meaning "Good birth can't be bought."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bíbí-ire
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bíbí - birthire - good, noble
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL