Béyìòkú
Sísọ síta
Ìtumọọ Béyìòkú
If this one did not die.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is an àbíkú name. See also: Bétikú, Bíòbákú.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bí-èyí-ò-kú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bí - ifèyí - this (one)
ò - does not
kú - die
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL