Bamọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Bamọ̀

Father did not know.



Àwọn àlàyé mìíràn

A child born after their father has died.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-à-mọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
à - did not
mọ̀ - know


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Baàmọ̀