Bajẹ́mitọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Bajẹ́mitọ́

Father let me be proper.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Fájẹ́mitọ́



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ba-jẹ́-mi-tọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ba - with
jẹ́ - let
mi - me
tọ́ - lead, guide


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL