Baiyékùsí

Sísọ síta



Ìtumọọ Baiyékùsí

What is left of the world.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ibi-aiyé-kù-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ibi - the place (where)
aiyé - world, earth
kù - remain
sí - exist


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL