Babalájé
Sísọ síta
Ìtumọọ Babalájé
Business father.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
baba-ní-ajé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
baba - fatherní - inside of
ajé - the spirit of resourcefulness, business
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Chief Saliu A.O. Adetunji Babalájé
the 41st Olúbàdàn of Ìbàdàn.