Babalọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Babalọlá
Father/Fatherhood is wealth/nobility/success.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
baba-ni-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
baba - fatherni - is
ọlá - wealth, nobility
-
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Babalọlá Bórìshàdé (four times Nigerian federal minister)