Babáwálé

Sísọ síta



Ìtumọọ Babáwálé

Father returned home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-wá-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
wá - come, return
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Wálé