Babátúnbọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Babátúnbọ́lá
Father gave birth to wealth again.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
baba-tún-bí-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
baba - fathertún - again
bí - give birth to
ọlá - wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO