Babátọ́pẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Babátọ́pẹ́

Father is worth being thankful for.



Àwọn àlàyé mìíràn

Can also be seen as a contraction of "Bàbá tó fún l'ọ́pẹ́" which would mean Father or God is worth giving praise to.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-tó-ọpẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
tó - enough for, suffice for
ọpẹ́ - joy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Ebenezer Babátọ́pẹ́. Nigerian politician.



Irúurú

Tọ́pẹ́