Babáfẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Babáfẹ́mi

Father loves me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-fẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
fẹ́ - love, admire, want
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fẹ́mi