Babáfúnkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Babáfúnkẹ́

The father gave me this (child) to care for.



Àwọn àlàyé mìíràn

In this name baba may also refer to God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-fún-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
fún - for
kẹ́ - to care for, to cherish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Babáfúnkẹ́ Ajáṣin

  • wife of Michael Ajáṣin

  • former governor of Ondo state.



Irúurú

Fúnkẹ́