Babádùnní

Sísọ síta



Ìtumọọ Babádùnní

A father is sweet to have.



Àwọn àlàyé mìíràn

See Ìyádùnní.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

baba-dùn-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

baba - father
dùn - sweet
- have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Dùnní