Bárátúndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bárátúndé

1. When the relatives returned. 2. When the bodies return. 3. When wonders return. (Baràtúndé)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-ará-tún-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - like
ará - relatives, kin
ara - body, bodies
àrà - wonder
tún - again, repeatedly
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Bárátúndé R. Thurston

  • Futurist comedian

  • writer

  • and cultural critic. Formerly of The Daily Show.