Bántálẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Bántálẹ́

Grow old with me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-n-tó-alẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - together with
n - me
tó - reach
alẹ́ - night, evening


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL