Bádéjọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Bádéjọ

Be at one with the crown



Àwọn àlàyé mìíràn

A shortening of names like Odùbádéjọ, Okùbádéjọ, Ògúnbádéjọ, etc. See also: Bóyèjọ.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-adé-jọ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- together with
adé - crown, royalty, nobility
jọ - together, in collaboration


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọmọ́bádéjọ

Àyánbádéjọ

Odùbádéjọ

Okùbádéjọ

Ògúnbádéjọ

Olúbádéjọ.