Bámigbádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bámigbádé

Help me carry the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-mi-gbé-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - help, join
mi - me
gbé - carry
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Bámgbádé

Bangbádé