Báfágúnwà
Sísọ síta
Ìtumọọ Báfágúnwà
Reign with Ifá.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Bọ́bagúnwà.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bá-ifá-gúnwà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bá - together withifá - the Ifá divination
gúnwà - reign, rule, sit at court
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL