Báatifẹ́órí

Sísọ síta



Ìtumọọ Báatifẹ́órí

As we wanted it to be (that's how it is).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-a-ti-fẹ́-kí-ó-rí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - as
a - we
ti - have
fẹ́ - want
kí - that
- it
rí - is


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL