Bọ́láwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ́láwá

One who comes with nobility.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-ọlá-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - together with
ọlá - wealth, nobility
wá - come, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
GENERAL