Bọ́lánílé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ́lánílé

Meet wealth at home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-ọlá-ní-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - meet
ọlá - wealth
ní - at, in
ilé - house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Bọ́lánlé

Bọ́lá