Bọ́lọ́rundúro

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ́lọ́rundúro

Standing with God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-ọlọ́run-dúró



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - together with
ọlọ́run - lord, God
dúró - wait, stand


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dúró