Bọ́lágbadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ́lágbadé

Help honor to collect the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-ọlá-gba-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- together with, meet
ọlá - honor, wealth, success
gba - to collect, to receive, to take
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mobọ́lágbadé

Bọ́lá

Gbadé