Bọ̀wọ̀fádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ̀wọ̀fádé

Give respect to the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bọ̀wọ̀-fún-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bọ̀wọ̀ - to give respect
fún - for, to
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL