Bọ̀bádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ̀bádé

Return to meet the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-ọba-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - together with
ọba - king
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Abọ́badé