Bẹ́kọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Bẹ́kọ̀
It isn't so.
Àwọn àlàyé mìíràn
The phonetic spelling of the name, more accurate, is Bẹ́ẹ̀kọ́.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bẹ́ẹ̀-kọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bẹ́ẹ̀ - like thatkọ́ - not
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Bẹ́ẹ̀kọ́ Ransome Kútì
medical doctor and human rights activist