Bíbírekòṣéfowórà
Sísọ síta
Ìtumọọ Bíbírekòṣéfowórà
A good/worthy birth is priceless.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bíbí-ire-kò-ṣeé-fi-owó-rà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bíbí - birth, pedigreeire - goodness
kò - does not/cannot
fi - use
owó - money
rà - buy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL