Bétikú
Sísọ síta
Ìtumọọ Bétikú
As long as he/she doesn't die.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a name given to àbíkú children. See also: Bíòbákú
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bí-è-ti-kú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bí - ifè - he/she
ti - have
kú - die
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
IJEBU