Bátifẹ́órí

Sísọ síta



Ìtumọọ Bátifẹ́órí

As we want it to be.



Àwọn àlàyé mìíràn

This comes from the common Yoruba song/prayer of thanks, "Bá ti fẹ́ ó rí, bẹ́ẹ̀ náà ló rí, emi la ò ní yọ̀ sí" - As we wanted it to be, that is how it came to be, why would we not rejoice.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-a-ti-fẹ́-órí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- like; as
a - we
ti - to, of
fẹ́ - love
órí - is how it looks


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL