Bámgbóyèga
Sísọ síta
Ìtumọọ Bámgbóyèga
Help me exalt (my) chieftaincy title.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bá-mi-gbé-oyè-ga
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bá - together withmi - me
gbé...ga - lift up
oyè - honour, glory, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL