Bájọmọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Bájọmọ
1. The king resembles the son. The father resembles the son. 2. The king is bigger than the son. The father is bigger than the son.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bàbá-jọ-ọmọ, ọba-jọ-ọmọ, bàbá-ju-ọmọ, ọba-jù-ọmọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bàbá - fatherọba - king
jọ - resemble
jù - be bigger than, be more prominent than
ọmọ - child
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL