Ayénúbèrun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayénúbèrun

The world is to be feared.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayé-ní-ùbẹ̀rùn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayé - earth, world, life
- to have, own
ùbẹ̀rùn - awe, fear (Ìbẹ̀rù)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ayéníbẹ̀rù