Ayénúbẹ̀rù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ayénúbẹ̀rù
The world is frightening.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ayé-ní-ì-bẹ̀rù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ayé - earth, world, lifení - have, own; in
ì - the act of
bẹ̀rù - be scared of, be respectful of, have in awe
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE