Ayọ̀olúwayímiká

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayọ̀olúwayímiká

The joy of the lord surrounds me.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is an expanded form of Yímiká or "Yínká"



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayọ̀-olúwa-yí-mi-ká



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayọ̀ - joy
olúwa - lord
yí...ká - surround
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ayọ̀

Ayọolú