Ayọ̀mípọ́si

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayọ̀mípọ́si

My happinness has gotten much more.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayọ̀-mi-pọ̀-síi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayọ̀ - joy, happiness
mi - mine
pọ̀ - plenty
síi - in addition


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Pọ̀síi

Pọ̀si