Ayọ̀kúnnú

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayọ̀kúnnú

Joy fills (my) inside.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayọ̀-kún-inú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayọ̀ - joy
kún - fill
inú - inside


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ayọ̀

Ayọ̀kúnnúmi