Ayẹnibíowó
Sísọ síta
Ìtumọọ Ayẹnibíowó
That which befits a person like money.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-yẹ-ẹni-bí-owó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one who; weyẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
ẹni - someone
bí - like
owó - money, cowries
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL