Awódigba
Sísọ síta
Ìtumọọ Awódigba
The priesthood/community has multipled.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
awo-di-igba
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious societydi - to become
igba - two hundred, plenteous
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI