Awóbífáwo
Sísọ síta
Ìtumọọ Awóbífáwo
A child born from one secret holder (member of a secret society/brotherhood) to another.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
awo-bí-fún-awo
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious societybí - to give birth to
fún - give to, gift to; for
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL