Awótúlà

Sísọ síta



Ìtumọọ Awótúlà

The Ifá priesthood has survived again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

awo-tú-là



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious society
- is worth (tó)
- to survive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO
OKITIPUPA



Irúurú

Awótúnlà

Túlà