Awórelé
Sísọ síta
Ìtumọọ Awórelé
Ifá priest/initiate has gone home.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a name given to a child born after the death of a prominent member of the family.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
awo-re-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
awo - priesthoodrè - reached, headed to
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL