Awókúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Awókúnlé

The Ifá priest has filled the house; The house is filled with Ifá priests.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

awo-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious society
kún - fill, add to
ilé - home, house, household


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Kúnlé