Awódùsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Awódùsì

The Ifá priest has become notable.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

awo-di-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious society
di - become
ùsì - fame, reputation


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI