Awódùmílà

Sísọ síta



Ìtumọọ Awódùmílà

The Ifá oracle struggled for me successfully.



Àwọn àlàyé mìíràn

See Fádùmílà, Ògúndùmílà.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

awo-dù-mí-là



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

awo - Ifá oracle, Ifá priest; cult or secret religious society
- struggle
- me
- to survive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Dùmílà