Atáyéṣe

Sísọ síta



Ìtumọọ Atáyéṣe

One who repairs the world/life.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

A-tún-ayé-ṣe



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

A - one who
tún...ṣe - fixes, repair
ayé - world, life, the Earth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Táyéṣe