Atánbíyí
Sísọ síta
Ìtumọọ Atánbíyí
Atan has given birth to this (child).
Àwọn àlàyé mìíràn
More properly written as Atánbíyìí.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
atan-bí-èyí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
atan - Atan (Akure/Ekiti river goddess)bí - to give birth to
èyí - this
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE